Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí àwa ṣa wà nínú èwu, nítórí rògbòdìyàn tí ó bẹ́ sílẹ̀ lóní yìí; kò sáá ní ìdí kan tí ìwọ́jọ yìí fi bẹ́ sílẹ̀.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:35-41