Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n bí ẹ ba ń wádìí ohun kan nípa ọ̀ràn mìíràn, a ó parí rẹ̀ ni àjọ tí ó tọ́.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:32-41