Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wí pé, “Ǹjẹ́ irú bamítíìsímù wo ni a bamitíìsímù yín sí?”Wọ́n sì wí pé, “Sí bamitíìsímù tí Jòhánù.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:1-8