Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wí fún wọn pé, “Ẹ̀yin ha gba Ẹ̀mi Mímọ́ náà nígbà tí ẹ̀yin gbàgbọ́?”Wọ́n sì wí fún un pé, “Àwa kò gbọ́ rárá pé Ẹ̀mí Mímọ́ kan wà.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:1-4