Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ń fọ̀rọ̀ wé ọ̀rọ̀ fún wọn nínú ṣínágógù lọ́jọjọ́ ìsinmi, ó sì ń yí àwọn Júù àti àwọn Gíríkì lọ́kàn padà.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:3-8