Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí tí o sọ àsọyé fún àwọn Júù ní gbangba, ó ń fi í hàn nínú ìwé-mímọ́ pé, Jésù ni Kíríṣítí.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:25-28