Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n wí pé, “Ọkùnrin yìí ń yí àwọn ènìyàn lọ́kàn padà, láti máa sin Ọlọ́run lòdì sí òfin.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:3-22