Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n sì gbà ògo lọ́wọ́ Jásónì àti àwọn ìyókù, wọ́n fi wọ́n ṣílẹ̀ lọ.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:6-12