Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lọ́gán àwọn arákùnrin sì rán Pọ́ọ̀lù àti Ṣílà lọ ṣí Béróéá lóru: nígbà tí wọ́n sí dé ibẹ̀, wọ́n wọ inú ṣínágógù àwọn Júù lọ.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:9-16