Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni a kì í fi ọwọ́ ènìyàn sìn ín, bí ẹni pé ó ń fẹ́ nǹkan, òun ni ó fi ìyè àti èémí àti ohun gbogbo fún gbogbo ènìyàn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:15-30