Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọlọ́run náà tí ó dá ayé àti ohun gbogbo tí ń bẹ nínú rẹ̀, òun náà tí í ṣe Olúwa ọ̀run àti ayé, kì í gbé ilé tí a fi ọwọ́ kọ́;

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:23-30