Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Onítúbú sì sọ ọ̀rọ̀ náà fún Pọ́ọ̀lù, wí pé, “Àwọn onídájọ́ ránṣẹ́ pé kí á da yín ṣílẹ̀: ǹjẹ́ nisinsìnyìí ẹ jáde kí ẹ sì máa lọ ní àlàáfíà.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:33-40