Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Pọ́ọ̀lù gbé ohun rẹ̀ sókè, wí pé, “Má se pa ara rẹ lára: nítorí gbogbo wa ń bẹ níhìn yìí!”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:25-29