Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí onítúbú si tají, tí o sì ri pé, àwọn ìlẹ̀kùn túbú tí sí sílẹ̀, ó fa idà rẹ̀ yọ, ó sì fẹ́ pa ara rẹ̀, ó ṣebí àwọn ara túbú ti sá lọ.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:17-32