Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ó sì tí rí ìran náà, lọ́gán ó múra láti lọ sí Makedóníà, a gbà á sí pé, Olúwa tí pè wá láti wàásù ìyìn rere fún wọn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:7-11