Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọn sì pẹ́, díẹ̀, àwọn arákùnrin rán wọn padà lọ ni àlàáfíà sí ọ̀dọ̀ àwọn tí ó rán wọn wá.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:30-38