Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Júdà àti Sílà tìkara wọn ti jẹ́ wòlíì pẹ̀lú, wọ́n fi ọ̀rọ̀ púpọ̀ gba àwọn arákùnrin níyànjú, wọ́n sì mú wọn lọ́kàn le.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:27-41