Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ó dára lójú Ẹ̀mí Mímọ́, àti lójú wa, kí a má ṣe di ẹrù kà yín, bí kò ṣe àwọn nǹkan wọ̀nyí tí ó ṣe pàtàkì;

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:25-31