Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà àwa rán Júdà àti Sílà àwọn tí yóò sì fi ọ̀rọ̀ ẹnu sọ ohun kan náà fún yín.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:21-37