Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n àwa gbàgbọ́ pé nípa oore-ọ̀fẹ́ Olúwa Jésù àwa ó là, gẹ́gẹ́ bí àwọn.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:10-15