Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ nítorí náà è é ṣe tí ẹ̀yin o fi dán Ọlọ́run wò, láti fi àjàgà bọ àwọn ọmọ-ẹ̀yìn lọ́rùn, èyí tí àwọn baba wa àti àwa kò lè rù?

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 15:2-14