Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àwọn aláìkọlà, àti àwọn Júù pẹ̀lú àwọn olórí wọn ti fẹ́ kọlù wọ́n láti fi àbùkù kàn wọ́n, àti láti sọ wọ́n ní òkúta,

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:1-14