Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn ìlú náà pín sí méjì: apákan dàpọ̀ mọ́ àwọn Júù, apákan pẹ̀lú àwọn àpósítélì.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:1-5