Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wà lọ́dọ̀ Ségíù Páúlúsì baálẹ̀ ìlú náà, amòye ènìyàn. Òun náà ni ó ránṣẹ́ pe Bánábà àti Ṣọ́ọ̀lù, nítorí tí ó fẹ́ gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:3-16