Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n nígbà tí àwọn Júù rí ọ̀pọ̀ ènìyàn náà, wọ́n kún fún owú, wọ́n ń sọ̀rọ̀-òdì sí ohun ti Pọ́ọ̀lù ń sọ.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:39-51