Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ ìsinmi kejì, gbogbo ìlú sí fẹ́rẹ̀ pejọ́ tan lati gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:41-46