Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n sì ti gbààwẹ̀, tí wọn sì ti gbàdúrà, wọ́n gbé ọwọ́ lé wọn, wọ́n sì rán wọn lọ.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:1-10