Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí wọn sì ti ń jọ́sìn fún Olúwa, tí wọ́n sì ń gbààwẹ̀, Ẹ̀mí Mímọ́ wí pé, “Ẹ ya Bánábà àti Ṣọ́ọ̀lù sọ́tọ̀ fún mi fún iṣẹ́ ti mo ti pè wọ́n sí!”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:1-7