Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lójúkan náà, nítorí ti Hẹ́rọ́dù kò fi ògo fún Ọlọ́run, ańgẹ́lì Olúwa lù ú, ó sì kú, ìdin sì jẹ ẹ́.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 12:22-25