Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn sì pinnu, olúkúlùkù gẹ́gẹ́ bí agbára rẹ̀ ti tó, láti rán ìrànlọ́wọ́ sí àwọn arakùnrin tí ó wà ní Jùdíà.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:28-30