Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ wọ̀nyí ni àwọn wòlíì sì ti Jerúsálémù sọ̀kalẹ̀ wá sí Áńtíókù.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:26-28