Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìròyìn nípa wọn sì dé etí ìjọ ti ó wà ni Jerúsálémù; wọ́n sì rán Bánábà lọ títí dé Áńtíókù;

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:19-30