Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọwọ́ Olúwa sì wà pẹ̀lú wọn: ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn sì gbàgbọ́, wọ́n sì yípadà sí Olúwa.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:11-22