Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kọ̀nẹ́líù sì dáhùn pé, “Ní ìjẹrin, mo ń ṣe àdúrà wákàtí kẹ́sàn-án ọjọ́ ni ilé mi títí di idayìí, sì wò ó, ọkùnrin kan aláṣọ, àlà dúró níwájú mi.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:21-31