Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà ni mo sì ṣe wá ní àìjiyàn, bí a ti ránṣẹ́ pè mi: ǹjẹ́ mo bèèrè, nítorí kín ní ẹ̀yin ṣe ránṣẹ́ pè mi?”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:24-31