Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wí fún wọn pé, “Kì í ṣe ti yín ni láti mọ àkókò tàbí ìgbà tí Baba ti yàn nípa àṣẹ òun tìkárarẹ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:1-17