Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí Jòhánù fi omi bamitíìsì yín, ṣùgbọ́n ní ọjọ́ díẹ̀ sí i, a o fi Ẹ̀mí Mímọ́ bamitíìsì yín.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:1-9