Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn sì gbàdúrà, wọn sì wí pé, “Olúwa, ìwọ mọ ọkàn gbogbo ènìyàn, fihàn wá nínú àwọn méjì yìí, èwo ni ìwọ yàn

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:17-26