Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn sì yan àwọn méjì, Jósẹ́fù tí a ń pè ní Básábà, (ẹni tí a sọ àpèlé rẹ̀ ni Júsítúsì) àti Màtíà.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:16-26