Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

(Júdásì fi èrè àìsòótọ́ rẹ̀ ra ilẹ̀ kan; nígbà tí ó sì subú ni ògèdèǹgbé, ó bẹ́ ní agbede-méjì, gbogbo ifun rẹ̀ sì tú jáde.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:11-26