Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nítorí ọ̀kan nínú wa ni òun ń se tẹ́lẹ̀, òun sì ní ìpín nínú iṣẹ́-ìránṣẹ́ yìí.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:13-26