Hósíà 4:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé o ṣe àgbèrè ìwọ Ísírẹ́lìÌdájọ́ yìí wà fún un yín Ẹ má ṣe jẹ́ kí Júdà di ẹlẹ́bi.“Ẹ má ṣe lọ sí Gílígálì.Ẹ má sì ṣe gòkè lọ sí Bẹti-ÁfénìẸ má sì búra pé, ‘Bí Olúwa ti wà láàyè nítòótọ́!’

Hósíà 4

Hósíà 4:13-16