Hósíà 4:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi kò ní jẹ àwọn ọmọbìnrin yínníyà nígbà tí wọ́n bá ṣe àgbèrètàbí àwọn àfẹ́sọ́nà ọmọ yín,nígbà tí wọ́n bá ṣe àgbèrènítorí pé àwọn ọkùnrin pàápàá ń bá alágbèrè kẹ́gbẹ́.Wọ́n sì ń rúbọ pẹ̀lú àwọn alágbèrè ilé òrìṣà.Nítorí náà, ènìyàn tí kò bá ní òye yóò parun!

Hósíà 4

Hósíà 4:5-19