Hósíà 4:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n ń gba ìmọ̀ràn lọ́wọ́ ère igiỌ̀pá igi sì ń dá wọn lóhùn.Ẹ̀mí àgbèrè ti mú wọn sìnàwọ́n sì jẹ́ aláìṣòótọ́ sí Ọlọ́run wọn.

Hósíà 4

Hósíà 4:6-13