Hósíà 4:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

‘Wọ́n sì ti fi ara wọn’ fún àgbèrè,wọ́n fi ara wọn fún wáìnì àtijọ́àti tuntun èyí tó gba òye àwọn ènìyàn mi sọnù

Hósíà 4

Hósíà 4:2-19