Hósíà 12:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gílíádì ha burú bí?Àwọn ènìyàn rẹ̀ jẹ́ asán.Ǹjẹ́ wọ́n ń fi akọ màlúù rúbọ ní Gílígálì?Gbogbo pẹpẹ wọ́n sì dàbí ebènínú aporo oko.

Hósíà 12

Hósíà 12:10-13