Hósíà 12:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Éfúráímù ń jẹ afẹ́fẹ́;Ó n lépa afẹ́fẹ́ ìwọ̀ oòrùn ní gbogbo ọjọ́.Ó sì ń gbèrú nínú irọ́Ó dá májẹ̀mú pẹ̀lú ÁsíríàÓ si fi òróró ólífì ránsẹ́ sí Éjíbítì.

Hósíà 12

Hósíà 12:1-5