Hágáì 2:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ èso ha wà nínú abà bí? Títí di àkókò yìí, àjàrà àti igi ọ̀pọ̀tọ́ àti pómégíránátè, àti igi ólífì kò ì tíì so èso kankan.“ ‘Láti òní lọ ni èmi yóò bùkún fún-un yin.’ ”

Hágáì 2

Hágáì 2:17-20