Hábákúkù 3:18-19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

18. ṣùgbọ́n ṣíbẹ̀, èmi o layọ nínú Olúwaèmi yóò sí máa yọ nińú Ọlọ́run ìgbàla mi.

19. Olúwa Ọlọ́run ni agbára mi,òun yóò sí ṣe ẹsẹ̀ mi bí ẹsẹ̀ àgbọ̀nrín,yóò sí mú mi rìn lórí ibi gíga.Ṣi olórí akọrin lórí ohun èlò orin olókùn mi.

Hábákúkù 3