Hábákúkù 2:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Olúwa wà nínú tẹ́ḿpílì mímọ́ rẹ̀;Ẹ jẹ́ kí gbogbo ayé pa rọ́rọ́ níwájú rẹ.”

Hábákúkù 2

Hábákúkù 2:16-20